Kronika Keji 1:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti Ijipti ati Kue ni Solomoni ti ń kó ẹṣin wá, àwọn oníṣòwò tí wọn ń ṣiṣẹ́ fún un ni wọ́n ń ra àwọn ẹṣin náà wá láti Kue.

Kronika Keji 1

Kronika Keji 1:9-17