Kọrinti Kinni 9:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ta ló jẹ́ ṣe iṣẹ́ ọmọ-ogun tí yóo tún máa bọ́ ara rẹ̀? Ta ló jẹ́ dá oko láì má jẹ ninu èso rẹ̀? Ta ló jẹ́ máa tọ́jú aguntan láìmu ninu wàrà aguntan tí ó ń tọ́jú?

Kọrinti Kinni 9

Kọrinti Kinni 9:1-9