Kọrinti Kinni 9:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé a kò ní ẹ̀tọ́ láti máa mú aya lọ́wọ́ ninu ìrìn àjò wa gẹ́gẹ́ bí àwọn aposteli yòókù ati àwọn arakunrin Oluwa ati Peteru?

Kọrinti Kinni 9

Kọrinti Kinni 9:3-10