Kọrinti Kinni 9:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣebí mo ní òmìnira? Ṣebí aposteli ni mí? Ṣebí mo ti rí Jesu Oluwa wa sójú? Ṣebí àyọrísí iṣẹ́ mi ninu Oluwa ni yín?

Kọrinti Kinni 9

Kọrinti Kinni 9:1-6