Kọrinti Kinni 8:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà nípa oúnjẹ tí a fi rúbọ fún oriṣa, a mọ̀ pé oriṣa kò jẹ́ nǹkankan ninu ayé. Ati pé kò sí Ọlọrun mìíràn àfi ọ̀kan ṣoṣo.

Kọrinti Kinni 8

Kọrinti Kinni 8:1-9