Kọrinti Kinni 8:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀ ń fi bẹ́ẹ̀ dẹ́ṣẹ̀ sí àwọn arakunrin yín tí ó jẹ́ aláìlera, ẹ̀ ń dá ọgbẹ́ sí ọkàn wọn, ẹ sì ń fi bẹ́ẹ̀ dẹ́ṣẹ̀ sí Kristi.

Kọrinti Kinni 8

Kọrinti Kinni 8:3-13