Kọrinti Kinni 7:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí obinrin onigbagbọ bá ní ọkọ tí kì í ṣe onigbagbọ, tí ó bá wu ọkọ rẹ̀ láti máa bá a gbé, kí ó má ṣe kọ ọkọ rẹ̀.

Kọrinti Kinni 7

Kọrinti Kinni 7:12-19