Kọrinti Kinni 6:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Àbí, ẹ kò mọ̀ pé ara yín ni ibùgbé Ẹ̀mí Mímọ́ tí ó wà ninu yín, tí ẹ gbà láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun? Ati pé kì í ṣe ẹ̀yin ni ẹ ni ara yín?

Kọrinti Kinni 6

Kọrinti Kinni 6:13-20