Kọrinti Kinni 6:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Àbí ẹ kò mọ̀ pé ẹni tí ó bá alágbèrè lòpọ̀ ti di ara kan pẹlu rẹ̀? Ìwé Mímọ́ sọ pé. “Àwọn mejeeji yóo di ara kan.”

Kọrinti Kinni 6

Kọrinti Kinni 6:9-20