Kọrinti Kinni 5:12-13 BIBELI MIMỌ (BM)

Èwo ni tèmi láti dá alaigbagbọ lẹ́jọ́? Ṣebí àwọn onigbagbọ ara yín ni ẹ̀ ń dá lẹ́jọ́? Ọlọrun ni ó ń ṣe ìdájọ́ àwọn alaigbagbọ. Ẹ yọ ẹni burúkú náà kúrò láàrin yín.

Kọrinti Kinni 5

Kọrinti Kinni 5:1-12-13