Kọrinti Kinni 5:1 BIBELI MIMỌ (BM)

A gbọ́ dájúdájú pé ìwà àgbèrè wà láàrin yín, irú èyí tí kò tilẹ̀ sí láàrin àwọn tí kì í ṣe Juu. A gbọ́ pé ẹnìkan ń bá iyawo baba rẹ̀ lòpọ̀!

Kọrinti Kinni 5

Kọrinti Kinni 5:1-10