Kọrinti Kinni 4:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ta ni ó gbe yín ga ju ẹlòmíràn lọ? Kí ni ohun tí ẹ dá ní, tí kò jẹ́ pé ọwọ́ Ọlọrun ni ẹ ti rí i gbà? Kí wá ni ìdí ìgbéraga yín bí ẹni pé ẹ̀yin ni ẹ dá a ní?

Kọrinti Kinni 4

Kọrinti Kinni 4:5-17