Kọrinti Kinni 4:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn mò ń bọ̀ láìpẹ́, bí Oluwa bá fẹ́. N óo wá mọ agbára tí àwọn tí wọn ń gbéraga ní nígbà náà, yàtọ̀ sí ọ̀rọ̀ ẹnu wọn lásán.

Kọrinti Kinni 4

Kọrinti Kinni 4:14-21