Kọrinti Kinni 3:22 BIBELI MIMỌ (BM)

ati Paulu ni, ati Apolo, ati Peteru, ati ayé yìí, ati ìyè, ati ikú, ati àwọn nǹkan ìsinsìnyìí ati àwọn nǹkan àkókò tí ń bọ̀, tiyín ni ohun gbogbo.

Kọrinti Kinni 3

Kọrinti Kinni 3:12-23