Kọrinti Kinni 3:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí iṣẹ́ ẹnikẹ́ni bá jóná, olúwarẹ̀ yóo pòfo, ṣugbọn òun alára yóo lá, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé bí ẹni tí a fà yọ ninu iná ni.

Kọrinti Kinni 3

Kọrinti Kinni 3:11-20