Kọrinti Kinni 3:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí kò sí ìpìlẹ̀ kan tí ẹnikẹ́ni tún lè fi lélẹ̀ mọ́, yàtọ̀ sí èyí tí Ọlọrun ti fi lélẹ̀, tíí ṣe Jesu Kristi.

Kọrinti Kinni 3

Kọrinti Kinni 3:10-12