Kọrinti Kinni 2:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ní tiwa, kì í ṣe ẹ̀mí ti ayé ni a gbà. Ẹ̀mí láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun ni ó fi fún wa, kí á lè mọ àwọn ẹ̀bùn tí Ọlọrun ti fún wa.

Kọrinti Kinni 2

Kọrinti Kinni 2:3-16