Kọrinti Kinni 16:23-24 BIBELI MIMỌ (BM) Kí oore-ọ̀fẹ́ Oluwa wa Jesu kí ó wà pẹlu yín. Mo fi ìfẹ́ kí gbogbo yín ninu Kristi Jesu.