Kọrinti Kinni 16:22-24 BIBELI MIMỌ (BM)

22. Bí ẹnikẹ́ni kò bá fẹ́ràn Oluwa wa, ẹni ègún ni! Marana ta–Oluwa wa, máa bọ̀!

23. Kí oore-ọ̀fẹ́ Oluwa wa Jesu kí ó wà pẹlu yín.

24. Mo fi ìfẹ́ kí gbogbo yín ninu Kristi Jesu.

Kọrinti Kinni 16