Kọrinti Kinni 16:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Inú mi dùn nígbà tí Stefana ati Fotunatu ati Akaiku dé, nítorí dídé tí wọ́n dé dí àlàfo tí ó ṣí sílẹ̀ nítorí àìsí yín lọ́dọ̀ wa.

Kọrinti Kinni 16

Kọrinti Kinni 16:8-24