Kọrinti Kinni 16:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Timoti bá dé, kí ẹ rí i pé ẹ fi í lára balẹ̀ láàrin yín, nítorí iṣẹ́ Oluwa tí mò ń ṣe ni òun náà ń ṣe.

Kọrinti Kinni 16

Kọrinti Kinni 16:5-16