Kọrinti Kinni 16:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nípa ti ìtọrẹ tí ẹ̀ ń ṣe fún àwọn eniyan Ọlọrun, bí mo ti ṣe ètò pẹlu àwọn ìjọ Galatia, bẹ́ẹ̀ gan-an ni kí ẹ̀yin náà máa ṣe.

Kọrinti Kinni 16

Kọrinti Kinni 16:1-4