Kọrinti Kinni 15:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí èmi ni mo kéré jùlọ ninu àwọn aposteli. N kò tilẹ̀ yẹ ní ẹni tí wọn ìbá máa pè ní aposteli, nítorí pé mo ṣe inúnibíni sí ìjọ Ọlọrun.

Kọrinti Kinni 15

Kọrinti Kinni 15:1-10