Kọrinti Kinni 15:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà ó tún fara han ẹẹdẹgbẹta (500) àwọn onigbagbọ lẹ́ẹ̀kan náà. Ọpọlọpọ ninu wọn wà títí di ìsinsìnyìí, ṣugbọn àwọn mìíràn ti kú.

Kọrinti Kinni 15

Kọrinti Kinni 15:1-15