Kọrinti Kinni 15:53 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ara tíí bàjẹ́ yìí níláti gbé ara tí kì í bàjẹ́ wọ̀; ara tí yóo kú yìí níláti gbé ara tí kì í kú wọ̀.

Kọrinti Kinni 15

Kọrinti Kinni 15:43-54