Kọrinti Kinni 15:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀tọ̀ ni ẹwà oòrùn, ọ̀tọ̀ ni ti òṣùpá, ọ̀tọ̀ ni ti àwọn ìràwọ̀, ìràwọ̀ ṣá yàtọ̀ sí ara wọn ní ẹwà.

Kọrinti Kinni 15

Kọrinti Kinni 15:31-51-52