Kọrinti Kinni 15:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ohun kinni tí ó ṣe pataki jùlọ tí èmi fúnra mi kọ́, tí mo sì fi kọ́ yín ni pé Kristi kú nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wa, gẹ́gẹ́ bí Ìwé Mímọ́ ti wí.

Kọrinti Kinni 15

Kọrinti Kinni 15:1-6