Kọrinti Kinni 15:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún ku nǹkankan! Nítorí kí ni àwọn kan ṣe ń ṣe ìrìbọmi nítorí àwọn tí ó kú? Bí a kò bá ní jí àwọn òkú dìde, kí ni ìdí rẹ̀ tí wọ́n fi ń ṣe ìrìbọmi nítorí wọn?

Kọrinti Kinni 15

Kọrinti Kinni 15:27-38