Kọrinti Kinni 15:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà ni òpin yóo dé, lẹ́yìn tí ó bá ti dá ìjọba pada fún Ọlọrun Baba, tí ó sì ti pa gbogbo àṣẹ, ọlá ati agbára run.

Kọrinti Kinni 15

Kọrinti Kinni 15:23-34