Kọrinti Kinni 15:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn òtítọ́ ọ̀rọ̀ yìí ni pé a ti jí Kristi dìde kúrò ninu òkú, òun sì ni àkọ́bí ninu àwọn tí wọ́n kú.

Kọrinti Kinni 15

Kọrinti Kinni 15:13-27