Kọrinti Kinni 15:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó jẹ́ pé, à ń kéde pé Kristi jinde kúrò ninu òkú, báwo ni àwọn kan ninu yín ṣe wá ń wí pé kò sí ajinde òkú?

Kọrinti Kinni 15

Kọrinti Kinni 15:3-14