Kọrinti Kinni 14:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí àwọn nǹkan tí kò ní ẹ̀mí tí à ń fi kọ orin, bíi fèrè tabi dùùrù, kò bá dún dáradára, ta ni yóo mọ ohùn orin tí wọn ń kọ?

Kọrinti Kinni 14

Kọrinti Kinni 14:1-17