Kọrinti Kinni 14:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹnikẹ́ni bá rò pé wolii ni òun tabi pé òun ní agbára Ẹ̀mí, kí olúwarẹ̀ mọ̀ pé àṣẹ láti ọ̀dọ̀ Oluwa ni ohun tí mo kọ ranṣẹ si yín yìí.

Kọrinti Kinni 14

Kọrinti Kinni 14:36-40