Kọrinti Kinni 14:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ohun ìkọ̀kọ̀ ọkàn rẹ̀ yóo hàn kedere, ni yóo bá dojúbolẹ̀, yóo sì júbà Ọlọrun. Yóo sọ pé, “Dájúdájú Ọlọrun wà láàrin yín.”

Kọrinti Kinni 14

Kọrinti Kinni 14:22-33