Kọrinti Kinni 14:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ máa lépa ìfẹ́. Ṣugbọn ẹ tún máa tiraka láti ní Ẹ̀mí Mímọ́, pàápàá jùlọ, ẹ̀bùn ìsọtẹ́lẹ̀.

Kọrinti Kinni 14

Kọrinti Kinni 14:1-5