Kọrinti Kinni 13:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìfẹ́ a máa mú sùúrù, a máa ṣe oore. Ìfẹ́ kì í jowú, kì í ṣe ìgbéraga, bẹ́ẹ̀ ni kì í fọ́nnu.

Kọrinti Kinni 13

Kọrinti Kinni 13:1-6