Kọrinti Kinni 13:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí mo wà ní ọmọde, èmi a máa sọ̀rọ̀ bí ọmọde, èmi a máa gbèrò bí ọmọde, ṣugbọn nisinsinyii tí mo ti dàgbà, mo ti pa ìwà ọmọde tì.

Kọrinti Kinni 13

Kọrinti Kinni 13:6-13