Kọrinti Kinni 12:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹlòmíràn ní igbagbọ, láti ọ̀dọ̀ Ẹ̀mí kan náà, ẹlòmíràn ní ẹ̀bùn láti ṣe ìwòsàn, láti ọ̀dọ̀ Ẹ̀mí kan náà;

Kọrinti Kinni 12

Kọrinti Kinni 12:4-15