Kọrinti Kinni 12:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Oríṣìíríṣìí ni ẹ̀bùn Ẹ̀mí Mímọ́ ṣugbọn láti ọ̀dọ̀ Ẹ̀mí kan náà ni wọ́n ti ń wá.

Kọrinti Kinni 12

Kọrinti Kinni 12:1-9