Kọrinti Kinni 12:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo yín ni aposteli bí? Àbí gbogbo yín ni wolii? Ṣé gbogbo yín ni olùkọ́ni? Àbí gbogbo yín ni ẹ lè ṣe iṣẹ́ ìyanu?

Kọrinti Kinni 12

Kọrinti Kinni 12:27-31