Kọrinti Kinni 12:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ẹ̀yà mìíràn tí a rò pé wọn kò dùn ún wò ni à ń dá lọ́lá jù. Àwọn ẹ̀yà ara tí kò dùn ún wò ni à ń yẹ́ sí jùlọ.

Kọrinti Kinni 12

Kọrinti Kinni 12:18-25