Kọrinti Kinni 12:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ mọ̀ pé nígbà tí ẹ jẹ́ aláìmọ Ọlọrun, ẹ̀ ń bọ oriṣa tí kò lè fọhùn. À ń tì yín síwá sẹ́yìn.

Kọrinti Kinni 12

Kọrinti Kinni 12:1-11