Kọrinti Kinni 12:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀dọ̀ Ẹ̀mí kan ṣoṣo ni gbogbo ẹ̀bùn wọnyi ti wá; bí ó sì ti wù ú ni ó pín wọn fún ẹnìkọ̀ọ̀kan.

Kọrinti Kinni 12

Kọrinti Kinni 12:6-14