Kọrinti Kinni 11:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí kò tọ́ kí ọkunrin bo orí rẹ̀, nítorí àwòrán ati ògo Ọlọrun ni. Ṣugbọn ògo ọkunrin ni obinrin.

Kọrinti Kinni 11

Kọrinti Kinni 11:5-16