Kọrinti Kinni 11:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí èyí ni ọpọlọpọ ninu yín ṣe di aláìlera ati ọlọ́kùnrùn, tí ọpọlọpọ tilẹ̀ ti kú.

Kọrinti Kinni 11

Kọrinti Kinni 11:28-34