Kọrinti Kinni 11:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí olukuluku yẹ ara rẹ̀ wò kí ó tó jẹ ninu burẹdi, kí ó sì tó mu ninu ife Oluwa.

Kọrinti Kinni 11

Kọrinti Kinni 11:18-29