Kọrinti Kinni 11:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí nígbàkúùgbà tí ẹ bá ń jẹ burẹdi yìí, tí ẹ sì ń mu ninu ife yìí, ẹ̀ ń kéde ikú Oluwa títí yóo fi dé.

Kọrinti Kinni 11

Kọrinti Kinni 11:21-33