Kọrinti Kinni 11:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí èyí, nígbà tí ẹ bá péjọ sí ibìkan náà, kì í ṣe Oúnjẹ Alẹ́ Oluwa ni ẹ̀ ń jẹ.

Kọrinti Kinni 11

Kọrinti Kinni 11:12-25