Kọrinti Kinni 11:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé láti ara ọkunrin ni obinrin ti wá, láti inú obinrin ni ọkunrin náà sì ti wá. Ṣugbọn ohun gbogbo ti ọ̀dọ̀ Oluwa wá.

Kọrinti Kinni 11

Kọrinti Kinni 11:6-19