Kọrinti Kinni 10:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni a kò gbọdọ̀ ṣe àgbèrè bí àwọn mìíràn ninu wọn ti ṣe àgbèrè, tí ọ̀kẹ́ kan ó lé ẹgbẹẹdogun (23,000) eniyan fi kú ní ọjọ́ kan.

Kọrinti Kinni 10

Kọrinti Kinni 10:1-9